Mátíù 27:1 BMY

1 Ní òwúrọ̀, gbogbo àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà Júù tún padà láti gbìmọ bí wọn yóò ti ṣe pa Jésù.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:1 ni o tọ