22 Pílátù béèrè pé, “Kí ni kí èmi ṣe sí Jésù ẹni ti a ń pè ní Kírísítì?”Gbogbo wọn sì tún kígbe pé, “Kàn án mọ́ àgbélébùú!”
Ka pipe ipin Mátíù 27
Wo Mátíù 27:22 ni o tọ