Mátíù 27:23 BMY

23 Pílátù sì béèrè pé, “Nítorí kí ni? Kí ló ṣe tí ó burú?”Wọ́n kígbe sókè pé, “Kàn án mọ́ àgbélébùú! Kàn án mọ́ àgbélébùú!”

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:23 ni o tọ