Mátíù 27:35 BMY

35 Lẹ́yìn tí wọ́n sì ti kàn án mọ́ àgbélébùú, wọ́n dìbò láti pín aṣọ rẹ̀ láàrin ara wọn.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:35 ni o tọ