Mátíù 27:34 BMY

34 Níbẹ̀ ni wọn ti fún un ni ọtí wáìnì tí ó ní egbòogi nínú láti mu. Ṣùgbọ́n nígbà tí ó tọ́ ọ wò, ó kọ̀ láti mu ún.

Ka pipe ipin Mátíù 27

Wo Mátíù 27:34 ni o tọ