17 Nígbà tí wọ́n sì rí i, wọ́n forí balẹ̀ fún un. Ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú wọn ṣe iyè méjì bóyá Jésù ni tàbí òun kọ́.
Ka pipe ipin Mátíù 28
Wo Mátíù 28:17 ni o tọ