Mátíù 5:21 BMY

21 “Ẹ̀yin ti gbọ́ bí a ti wí fún àwọn ará ìgbàanì pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ pànìyàn, ẹnikẹni tí ó bá pànìyàn yóò wà nínú ewu ìdájọ́.’

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:21 ni o tọ