Mátíù 5:46 BMY

46 Bí ẹ̀yin bá fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn yín nìkan, èrè kí ni ẹ̀yin ní? Àwọn agbowó-òde kò ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́?

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:46 ni o tọ