Mátíù 5:47 BMY

47 Àti bí ó bá sì jẹ́ pé kìkì àwọn arákùnrin yín nìkan ni ẹ̀yin ń kí, kín ni ẹ̀yin ń ṣe ju àwọn mìíràn? Àwọn abọ̀rìṣà kò ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ bí?

Ka pipe ipin Mátíù 5

Wo Mátíù 5:47 ni o tọ