Mátíù 6:1 BMY

1 “Ẹ kíyè ṣára kí ẹ má ṣe iṣẹ́ rere yín níwájú àwọn ènìyàn nítorí kí a le rí yín, Bí ẹ bá ṣe bẹ́ẹ̀, ẹ̀yin kò lérè kankan lọ́dọ̀ Baba yín ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:1 ni o tọ