Mátíù 6:20 BMY

20 Dípò bẹ́ẹ̀ to ìṣúra rẹ jọ sí ọ̀run, níbi ti kòkòrò àti ìpáàrà kò ti lè bà á jẹ́, àti ní ibi tí àwọn olè kò le fọ́ wọlé láti ji í lọ.

Ka pipe ipin Mátíù 6

Wo Mátíù 6:20 ni o tọ