Deu 10:20 YCE

20 Ki iwọ ki o ma bẹ̀ru OLUWA Ọlọrun rẹ; on ni ki iwọ ki o ma sìn, on ni ki iwọ ki o si faramọ́, orukọ rẹ̀ ni ki o si ma fi bura.

Ka pipe ipin Deu 10

Wo Deu 10:20 ni o tọ