Deu 10:21 YCE

21 On ni iyìn rẹ, on si li Ọlọrun rẹ, ti o ṣe ohun nla ati ohun ẹ̀lẹru wọnni fun ọ, ti oju rẹ ri.

Ka pipe ipin Deu 10

Wo Deu 10:21 ni o tọ