Deu 15:4 YCE

4 Ṣugbọn ki yio sí talaka ninu nyin; (nitoripe OLUWA yio busi i fun ọ pupọ̀ ni ilẹ na, ti OLUWA Ọlọrun rẹ fi fun ọ ni iní lati gbà a;)

Ka pipe ipin Deu 15

Wo Deu 15:4 ni o tọ