Deu 24:21 YCE

21 Nigbati iwọ ba nká eso ọgbà-àjara rẹ, ki iwọ ki o máṣe peṣẹ́ lẹhin rẹ: ki eyinì ki o jẹ́ ti alejò, ti alainibaba, ati ti opó.

Ka pipe ipin Deu 24

Wo Deu 24:21 ni o tọ