Deu 24:22 YCE

22 Ki iwọ ki o si ma ranti pe iwọ ti ṣe ẹrú ni ilẹ Egipti: nitorina ni mo ṣe paṣẹ fun ọ lati ma ṣe nkan yi.

Ka pipe ipin Deu 24

Wo Deu 24:22 ni o tọ