Deu 29:28 YCE

28 OLUWA si fà wọn tu kuro ni ilẹ wọn ni ibinu, ati ni ikannu, ati ni irunu nla, o si lé wọn lọ si ilẹ miran, bi o ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Deu 29

Wo Deu 29:28 ni o tọ