Deu 29:29 YCE

29 Ti OLUWA Ọlọrun wa ni ohun ìkọkọ: ṣugbọn ohun ti afihàn ni tiwa ati ti awọn ọmọ wa lailai, ki awa ki o le ma ṣe gbogbo ọ̀rọ ofin yi.

Ka pipe ipin Deu 29

Wo Deu 29:29 ni o tọ