Deu 3:8 YCE

8 Nigbana li awa gbà li ọwọ́ awọn ọba ọmọ Amori mejeji, ilẹ ti mbẹ ni ìha ẹ̀bá Jordani, lati afonifoji Arnoni lọ dé òke Hermoni;

Ka pipe ipin Deu 3

Wo Deu 3:8 ni o tọ