Deu 32:24 YCE

24 Ebi yio mu wọn gbẹ, oru gbigbona li a o fi run wọn, ati iparun kikorò; emi o si rán ehín ẹranko si wọn, pẹlu oró ohun ti nrakò ninu erupẹ.

Ka pipe ipin Deu 32

Wo Deu 32:24 ni o tọ