Deu 32:25 YCE

25 Idà li ode, ati ipàiya ninu iyẹwu, ni yio run ati ọmọkunrin ati wundia, ọmọ ẹnu-ọmu, ati ọkunrin arugbo elewu irun pẹlu.

Ka pipe ipin Deu 32

Wo Deu 32:25 ni o tọ