Deu 4:13 YCE

13 O si sọ majẹmu rẹ̀ fun nyin, ti o palaṣẹ fun nyin lati ṣe, ani ofin mẹwa nì; o si kọ wọn sara walã okuta meji.

Ka pipe ipin Deu 4

Wo Deu 4:13 ni o tọ