Deu 4:37 YCE

37 Ati nitoriti o fẹ́ awọn baba rẹ, nitorina li o ṣe yàn irú-ọmọ wọn lẹhin wọn, o si fi agbara nla rẹ̀ mú ọ lati Egipti jade wá li oju rẹ̀;

Ka pipe ipin Deu 4

Wo Deu 4:37 ni o tọ