Deu 4:38 YCE

38 Lati lé awọn orilẹ-ède jade kuro niwaju rẹ, ti o tobi, ti o si lagbara jù ọ lọ, lati mú ọ wọle, lati fi ilẹ wọn fun ọ ni iní, bi o ti ri li oni yi.

Ka pipe ipin Deu 4

Wo Deu 4:38 ni o tọ