Deu 7:10 YCE

10 Ti o si nsan a pada fun awọn ti o korira rẹ̀ li oju wọn, lati run wọn: on ki yio jafara fun ẹniti o korira rẹ̀, on o san a fun u loju rẹ̀.

Ka pipe ipin Deu 7

Wo Deu 7:10 ni o tọ