Deu 7:11 YCE

11 Nitorina ki iwọ ki o pa ofin, ati ìlana, ati idajọ mọ́, ti mo palaṣẹ fun ọ li oni, lati ma ṣe wọn.

Ka pipe ipin Deu 7

Wo Deu 7:11 ni o tọ