Deu 7:18 YCE

18 Ki iwọ ki o máṣe bẹ̀ru wọn: ṣugbọn ki iwọ ki o ranti daradara ohun ti OLUWA Ọlọrun rẹ ṣe si Farao, ati si gbogbo Egipti;

Ka pipe ipin Deu 7

Wo Deu 7:18 ni o tọ