11 O si ṣe li opin ogoji ọsán ati ogoji oru, ti OLUWA fi walã okuta meji nì fun mi, ani walã majẹmu nì.
Ka pipe ipin Deu 9
Wo Deu 9:11 ni o tọ