1 NJẸ orukọ awọn ọmọ Israeli, ti o wá si Egipti pẹlu Jakobu ni wọnyi; olukuluku pẹlu ile rẹ̀.
2 Reubeni, Simeoni, Lefi, ati Judah;
3 Issakari, Sebuluni, ati Benjamini;
4 Dani ati Naftali, Gadi ati Aṣeri.