Eks 1:17 YCE

17 Ṣugbọn awọn iyãgbà bẹ̀ru Ọlọrun, nwọn kò si ṣe bi ọba Egipti ti fi aṣẹ fun wọn, nwọn si da awọn ọmọkunrin si.

Ka pipe ipin Eks 1

Wo Eks 1:17 ni o tọ