Eks 10:20 YCE

20 Ṣugbọn OLUWA mu àiya Farao le, bẹ̃ni kò si jẹ ki awọn ọmọ Israeli ki o lọ.

Ka pipe ipin Eks 10

Wo Eks 10:20 ni o tọ