Eks 12:36 YCE

36 OLUWA si fun awọn enia na li ojurere li oju awọn ara Egipti, bẹ̃ni nwọn si fun wọn li ohun ti nwọn bère. Nwọn si kó ẹrù awọn ara Egipti.

Ka pipe ipin Eks 12

Wo Eks 12:36 ni o tọ