Eks 13:12 YCE

12 Ni iwọ o si yà gbogbo akọ́bi sọ̀tọ fun OLUWA, ati gbogbo akọ́bi ẹran ti iwọ ni; ti OLUWA li awọn akọ.

Ka pipe ipin Eks 13

Wo Eks 13:12 ni o tọ