Eks 14:16 YCE

16 Ṣugbọn iwọ gbé ọpá rẹ soke, ki iwọ ki o si nà ọwọ́ rẹ si oju okun ki o si yà a meji: awọn ọmọ Israeli yio si là ãrin okun na kọja ni iyangbẹ ilẹ.

Ka pipe ipin Eks 14

Wo Eks 14:16 ni o tọ