Eks 18:26 YCE

26 Nwọn si nṣe idajọ awọn enia nigbakugba: ọ̀ran ti o ṣoro, nwọn a mútọ̀ Mose wá, ṣugbọn awọn tikalawọn ṣe idajọ gbogbo ọ̀ran kekeké.

Ka pipe ipin Eks 18

Wo Eks 18:26 ni o tọ