Eks 18:9 YCE

9 Jetro si yọ̀ nitori gbogbo ore ti OLUWA ti ṣe fun Israeli, ẹniti o ti gbàla lọwọ awọn ara Egipti.

Ka pipe ipin Eks 18

Wo Eks 18:9 ni o tọ