Eks 19:10 YCE

10 OLUWA si wi fun Mose pe, Tọ̀ awọn enia yi lọ, ki o si yà wọn simimọ́ li oni ati li ọla, ki nwọn ki o si fọ̀ asọ wọn.

Ka pipe ipin Eks 19

Wo Eks 19:10 ni o tọ