Eks 19:21 YCE

21 OLUWA si wi fun Mose pe, Sọkalẹ, kìlọ fun awọn enia, ki nwọn ki o má ba yà sọdọ OLUWA lati bẹ̀ ẹ wò, ki ọ̀pọ ki o má ba ṣegbe ninu wọn.

Ka pipe ipin Eks 19

Wo Eks 19:21 ni o tọ