Eks 2:17 YCE

17 Awọn oluṣọ-agutan si wá, nwọn si lé wọn kuro: nigbana ni Mose dide duro, o ràn wọn lọwọ, o si fi omi fun agbo-ẹran wọn.

Ka pipe ipin Eks 2

Wo Eks 2:17 ni o tọ