Eks 20:23 YCE

23 Ẹnyin kò gbọdọ ṣe ọlọrun miran pẹlu mi; Ẹnyin kò gbọdọ ṣe ọlọrun fadaka, tabi ọlọrun wurà, fun ara nyin.

Ka pipe ipin Eks 20

Wo Eks 20:23 ni o tọ