Eks 22:29 YCE

29 Iwọ kò gbọdọ jafara lati mú irè oko rẹ wá, ati ọti rẹ. Akọ́bi awọn ọmọ rẹ ọkunrin ni iwọ o fi fun mi.

Ka pipe ipin Eks 22

Wo Eks 22:29 ni o tọ