Eks 25:17 YCE

17 Iwọ o si fi kìki wurà ṣe itẹ-anu: igbọnwọ meji on àbọ ni gigùn rẹ̀, ati igbọnwọ kan on àbọ ni ibú rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 25

Wo Eks 25:17 ni o tọ