Eks 29:13 YCE

13 Iwọ o si mú gbogbo ọrá ti o bò ifun lori, ati àwọn ti o bori ẹ̀dọ, ati ti iwe mejeji, ati ọrá ti o wà lara wọn, iwọ o si sun u lori pẹpẹ na.

Ka pipe ipin Eks 29

Wo Eks 29:13 ni o tọ