Eks 29:17 YCE

17 Iwọ o si kun àgbo na, iwọ o si fọ̀ ifun rẹ̀, ati itan rẹ̀, iwọ o si fi wọn lé ara wọn, ati lé ori rẹ̀.

Ka pipe ipin Eks 29

Wo Eks 29:17 ni o tọ