Eks 29:23 YCE

23 Ati ìṣu àkara kan, ati àkara kan ti a fi oróro din, ati àkara fẹlẹfẹlẹ kan kuro ninu agbọ̀n àkara alaiwu, ti o wà niwaju OLUWA:

Ka pipe ipin Eks 29

Wo Eks 29:23 ni o tọ