Eks 3:11 YCE

11 Mose si wi fun Ọlọrun pe, Tali emi, ti emi o fi tọ̀ Farao lọ, ati ti emi o fi le mú awọn ọmọ Israeli jade lati Egipti wá?

Ka pipe ipin Eks 3

Wo Eks 3:11 ni o tọ