Eks 3:20 YCE

20 Emi o si nà ọwọ́ mi, emi o si fi iṣẹ-iyanu mi gbogbo kọlù Egipti ti emi o ṣe lãrin rẹ̀: lẹhin eyinì li on o to jọwọ nyin lọwọ lọ.

Ka pipe ipin Eks 3

Wo Eks 3:20 ni o tọ