Eks 31:11 YCE

11 Ati oróro itasori, ati turari olõrùn didùn fun ibi mimọ́ nì: gẹgẹ bi gbogbo eyiti mo palaṣẹ fun ọ ni nwọn o ṣe.

Ka pipe ipin Eks 31

Wo Eks 31:11 ni o tọ