Eks 31:17 YCE

17 Àmi ni iṣe lãrin emi ati lãrin awọn ọmọ Israeli titilai: nitori ni ijọ́ mẹfa li OLUWA dá ọrun on aiye, ni ijọ́ keje o si simi, o si ṣe ìtura.

Ka pipe ipin Eks 31

Wo Eks 31:17 ni o tọ