Eks 32:3 YCE

3 Gbogbo awọn enia si kán oruka wurà ti o wà li eti wọn, nwọn si mú wọn tọ̀ Aaroni wá.

Ka pipe ipin Eks 32

Wo Eks 32:3 ni o tọ